Gospel singer, songwriter and Evangelist Gideon Ayodele Oluwasina has released a brand new single titled “Olorun MFM” (The God of MFM).
As a man who understands the art of compelling, inspiring, enjoining and alluring Christian praise worship music, Evang. Gideon Ayodele Oluwasina’s mission is to usher people into Praising God in songs, dancing and worshipping God unconditionally through the help of the Holy Spirit.
While sharing about the inspiration behind “Olorun MFM”, Evang. Gideon said he received the song during one of the MFM Power Must Change Hands fasting and prayers service from the Holy Spirit.
“When I remembered how God changed my life story from grass to Grace, from zero to Hero. And how God changed many lives in Mountain of Fire and Miracles Ministries for good. How a woman of age, 54years gave birth to twins and many other miracles i have witnessed in MFM, I was inspired and I received this wonderful Praise song from the Holy Spirit – The God of MFM, The great and mighty God, Lord Jesus you are immortal, Greater than the whole wide world“
Olorun MFM,
Olorun Algebra,
Aiku ni o oooo Je…su,
Oju gbogbo aye lo
Lead chorus ; Olorun mfm, olorun alagbara.
Aiku ni o o Jesu , o ju gbogbo aye lo.
Resp (Chorus) : Olorun mfm (Oba nla),
Olorun alagbara ( titobi ninu agbara ),
Aiku ni o o Jesu , o ju gbogbo aye lo.
(Olorun wa) Olorun mfm,(titobi ninu ola nla)
Olorun alagbara, (aiku Le ma je) aiku ni o o Jesu,
O ju gbogbo aye lo
Call : o maro larada. Resp: Oba wa.
Call : O ji oku dide. Resp : Oba ni.
Call : O Sagan dolomo.
Resp: Alaini deni ibukun.
Aiku ni o Jesu, O ju gbogbo aye lo.
( olorun wa)
Chorus : Olorun mfm……..(Titobi ninu ola o)
Call : Alagbara Lori aye.
Resp : Lori aye.
Call : Awogbaarun magbeje.
Resp : onisegun nla.
Call : Baba Alaini baba.
Resp : baba awa, oko awon opo.
Eh, Aiku ni o o Jesu, oju gbogbo aye lo.
(Olorun wa)
Chorus : Olorun mfm…… ( Oba nla nla),
(alagbara lori aye),(ese o)
Olorun wa.
Chorus : Olorun mfm…….. (Titobi ninu ola nla), ( ese o)
Call : e ju gbogbo ayeeee.
Resp : O ju gbogbo aye lo.
Call : Aiku Ni o, Ai Sa ni o, Ai piyinkin, Aidibaje, olorun OLUKOYA.
Oba to soriburuku dolori rereee. Resp : O ju gbogbo aye lo.
Call : O ju gbo gbo ayeee.
Resp : O ju gbogbo aye lo
Call : O ju gbogbo ayeee
Resp : o ju gbogbo aye lo
Call : O ju isoro wa lo.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
Call : o ju aini wa lo.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
Call : o ju iponju wa lo.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
Call : Oba nla le ma je.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
Call : Oba to n’omije mi nu.
Resp : O ju gbogbo aye lo.
Call : O so ekun mi derin.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
Call : Titobi ninu Ola nla.
Resp: o ju gbogbo aye lo.
Call : Ti tobi ninu agbara.
Resp : o ju gbogbo aye lo.
(Olorun wa)
Chorus : Olorun mfm….
(Oba nla ese o),(agbe o ga)
(Olorun wa)
Chorus : Olorun Mfm…
(Olorun Olukoya) , (ajamajebi baba),(ese o)
Chorus : Olorun mfm….
(Kabi o o si),
(alagbara nla),
(aikule je olorun wa o),(agbe o ga)
(Olorun wa)
Chorus : Olorun mfm……
(enikan soso ta gbojule),
(alatileyin Onigbagbo),(ese o)